Timothy’s Report – CAC Living Water Daily Devotional

THE LIVING WATER DAILY DEVOTIONAL GUIDE

Wednesday, February 3, 2021.

TOPIC: TIMOTHY’S REPORT

Read 1 Thessalonians 3:6-10
6 But now that Timothy has come to us from you, and brought us good news of your faith and love, and that you always have good remembrance of us, greatly desiring to see us, as we also to see you
7 therefore, brethren, in all our affliction and distress we were comforted concerning you by your faith.
8 For now we live, if you stand fast in the Lord.
9 For what thanks can we render to God for you, for all the joy with which we rejoice for your sake before our God,
10 night and day praying exceedingly that we may see your face and perfect what is lacking in your faith?

MEMORISSE:
As cold water to a weary soul, so is good news from a far country (Proverbs 25:25)

EXPOSITION
Report is usually detailed account or statement of something. It communicates the condition of a situation. Who gives you report about issues of life? Timothy took cheering news from Paul to the Thessalonian Church. The news that edifies, strengthens and encourages. The very words needed in time of trouble and despair. He equally had words that take away fear, the true picture of the Thessalonian brethren. The result that lessens their pains – the fruit of their labour is bountiful. Is anything more cheering? vv6-8. Does your report encourage other brethren? To Paul, it is good to know that the Thessalonians brethren remain faithful in the midst of trouble and persecution.
Nehemiah needed report about Jerusalem, he knew the men who really loved God and he approached them for the information. He looked for those who can give true picture of the happenings in Jerusalem. The information held him to take right steps. Let godly people be the source of your information.
Be the carrier comforting messages that lift man’s spirit, draw man to God; and give hope. Can your report be trusted?
The nature of report taken to others will inform their response, either to God or to the devil. Don’t be the evil reporter that takes people away from the grace offered by Christ. The only report to carry around is the Good News. It can’t be outdated; it’s new by the day. Think of one person daily who needs to hear the Good News and be sure it gets to him. This will surely comfort them as cold water to the thirsty. Imagine a cold cup of water from a friend after a long walk on a sunny day.

PRAYER POINTS

  1. I receive the grace to be a carrier of good news everywhere l go and in all my endeavours.
  2. Pray that God will pass through our churches for total cleansing, and renew right spirit within every congregant.
  3. Pray that God will uphold all believers to the end, in Jesus’ name.

EXTRA READING FOR TODAY:
Exodus 21:35 – 23:31; Matthew 21:45 – 22:20.

Yoruba

ÌJỌ ÀPỌ́SÍTÉLÌ KRISTI NÍ ÀGBÁYÉ
OMI IYE NÁÀ, (Oṣù Kínní – Oṣù Kẹfà, 2021)

Ọjọ
Ọjọ́ru (Wednesday), February 3, 2021

Ka
I Tẹsalóníkà 3:6-10

AKỌSORI
Bí omi tutu sì ọkàn tí o-n-gbẹ ń gbẹ, bẹẹni ìhìnrere láti ìlú òkèèrè wa

(Òwe 25:25).

IHIN/ỌRỌ TIMOTEU

ITUPALẸ
Ìhìn/ìròyìn jẹ àkójọpọ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé tàbí ọrọ nípa nnkan. O n sọ̀rọ̀ nípa ipo ti ìṣẹ̀lẹ̀ kan wa. Tani o n fún ọ ní Ìhìn nípa àwọn ọrọ/ìṣẹ̀lẹ̀ ayé? Timoteu mú ìròyìn rere láti ọ̀dọ̀ Pọ́ọ̀lù lọ sí Ìjọ Tẹsalóníkà. Ìròyìn to ń mú ní dàgbà, fún ní lókun àti múnílọ́kànle. Àwọn ọrọ ti ènìyàn nílò gan-an ni àkókò wàhálà àti ainireti. Bákan náà ni o ni àwọn ọrọ ti o n mú ẹrù kúrò, tí ìṣe àwòrán tòótọ́ àwọn ara Tẹsalóníkà. Àbájáde tí o mú adinku ba ìnira wọn – èso ìṣẹ́ wọn pọn púpọ̀. Ohunkóhun ha tún wa to mú inú ẹni dùn ju èyí lọ bi? Ẹsẹ 6-8. Ìhìn/ọrọ rẹ, a máa mú ọkàn àwọn ẹlòmíràn le bí? Sì Pọ́ọ̀lù, ó dára láti mọ pe àwọn ara Tẹsalóníkà jẹ ólotitọ síbẹ̀ nínú ìṣòro àti inúnibíni.
Nehemáyà ń fẹ́ ìhìn nípa Jerúsálẹ́mù, o mọ àwọn ọkùnrin tí wọ́n fẹ́ Ọlọ́run tọkàntọkàn, ó sì kan sì wọn fún ìhìn náà. O wa àwọn tí o le fún òun ní àwòrán òun ti o n ṣẹlẹ̀ ni Jerúsálẹ́mù gan-an lọ. Ìhìn náà mu kí o gbé àwọn igbesẹ tí o tọ́. Jẹ ki àwọn ènìyàn oníwà-bí-Ọlọ́run máa jẹ orísun ìhìn rẹ.
Jẹ ẹni tó ní àwọn ọrọ ìtura/imulọkanle tí ó ń rú ẹ̀mí/ọkàn ènìyàn sókè, fa ènìyàn sì ọdọ Ọlọ́run; kí o sì máa fún ni ni ìrètí. A ha le gbẹkẹle ìhìn rẹ bí?
Irú ìhìn tí a ba mú lọ sí ọdọ àwọn ẹlòmíràn ní yóò sọ ìdáhùn/igbesẹ wọn, yálà sì Ọlọ́run tàbí sí èṣù. Máṣe jẹ ẹni tó ń ro ìhìn búburú tó ń mú àwọn ènìyàn kúrò lábẹ́/nínú oore-ọ̀fẹ́ tí Kristi fífún ni. Ìhìn kanṣoṣo tí a ní láti máa ro káàkiri ní ìhìnrere náà. Ko le dibajẹ, ọtun-ọtun ni lojoojumọ. Máa ronú nípa ẹnikan lojoojumọ tí ó nílò láti gbọ ihinrere náà kì o sì rii dájú pé o dé ọdọ rẹ. O dájú pé èyí yóò mú ìtura ba wọn gẹ́gẹ́ bí omi tutu tíì ṣe si òùngbẹ. Ronú nípa bí yóò ti rí bí ọrẹ rẹ kan ba fún ọ ní ìfẹ́ omi tútù kan mú lẹ́yìn rìnrìn irin púpọ̀ nínú oòrùn.

ÀWỌN KÓKÓ ÀDÚRÀ

  1. Mo gbà oore-ọ̀fẹ́ láti jẹ ẹni tó ń gbé ìhìn réré káàkiri ibi gbogbo tí mo ba lọ àti nínú gbogbo ìdáwọ́lé mi.
  2. Gbàdúrà pé Ọlọ́run yóò la àwọn ìjọ wa kọjá fún iwẹnumọ pátápátá, yóò sì mú kí ẹ̀mí isọdọtun o wọnú ọmọ ìjọ kọ̀ọ̀kan.
  3. Gbàdúrà pé Ọlọ́run yóò di àwọn ònígbagbọ mú dópin ni orúkọ Jésù.

Àfikún Ibi Kíkà Fún Òní: Ẹ́kísódù 21:35 – 23:31; Mátíù 21:45 – 22:20.

You may also like...

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

%d bloggers like this: